Font Size
Eksodu 12:40
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Eksodu 12:40
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
40 (A)Iye ọdún ti àwọn ará Israẹli gbé ní ilẹ̀ Ejibiti jẹ́ irínwó ọdún ó-lé-ọgbọ̀n (430).
Read full chapter
Eksodu 12:41
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Eksodu 12:41
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
41 (A)Ó sì ní òpin irínwó ọdún ó le ọgbọ̀n (430), ní ọjọ́ náà gan an, ni ó sì ṣe tí gbogbo ogun Olúwa jáde kúrò ní ilẹ̀ Ejibiti.
Read full chapter
Ìṣe àwọn Aposteli 7:7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìṣe àwọn Aposteli 7:7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
7 (A)Ọlọ́run wí pé, Orílẹ̀-èdè náà tí wọn yóò máa sìn, ni èmi ó dá lẹ́jọ́; lẹ́yìn náà ni wọn ó sì jáde kúrò, wọn ó sì wá sìn mí níhìn-ín yìí.’
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.