Add parallel Print Page Options

Ìfojúsọ́nà Paulu láti bẹ Romu wò

(A)Ní àkọ́kọ́, mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nípasẹ̀ Jesu Kristi fún gbogbo yín, nítorí a ń ròyìn ìgbàgbọ́ yin káàkiri gbogbo ayé.

Read full chapter